Page:PeterRabbit1910.djvu/64

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ó ṣe mí láànú l'áti wí fún yín pé Pétérù kò gbádùn are rẹ̀ ní ìrọ̀lé ọjọ́ náà.

Ìyá rẹ̀ gbèè sórí i ibùsùn, ó sì ṣe àgbo; ó bu díẹ̀ fún Pétérù!

'Ẹ̀kún ṣíbí kan lo ma lò lálalẹ́.'