Page:PeterRabbit1910.djvu/61

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ọ̀gbẹ́ni McGregor fi kóòtù kékeré rẹ̀ kọ́gi pẹ̀lú àwọn bàtà rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi eégún adẹ́rùbẹyẹ, kí ó máa sẹ́rù ba àwọn ẹyẹ oko.