Page:PeterRabbit1910.djvu/57

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ó padà sí ọ̀nà Ilé-ìfirinṣẹ́pamọ́ṣí, sùgbọ́n lójijì, láti ibi tí kò jìnà síi rárá, ó gbọ́ ọkọ́ tí n kọlẹ̀—ki-iri, kirra, kirra, kirro. Pétérù bá yára lúgọ̀ọ́ sábẹ́ igbó. Ṣùgbọ́n lọ́wọ́lọ́wọ́, tí kò sí ǹkan tí ó sẹlẹ̀, ó jáde, ó sì gun ori kẹ̀kẹ́-akẹ́rù kan l'áti yọ jú wo ọ̀ọ́kán. Ohun tí ó kọ́kọ́ rí sìni Ọ̀gbẹ́ni McGregor tí óún roko àlùbọ́sà. Ó kọọ ẹ̀yìn rẹ̀ sí Pétérù, iwájú rẹ̀ lọhùń sì ni ilẹ̀kùn ńlá ọgbà wà!