Page:PeterRabbit1910.djvu/45

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ó sá wọnú ilé-ìkóriṣẹ́pamọ́ṣí, wéré ló kó sínu agolo níbẹ̀. Kì bá sì jẹ́ ibi tí ó wúlò láti sá pamó sí, bí kò ṣe wípé ò kún fún omi lẹ́kùńrẹ́rẹ́.