Page:PeterRabbit1910.djvu/42

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ọ̀gbẹ́ni McGregor yọ asẹ́ dání wá, tí ó ní lérò láti fi bo Pétérù mọ́lẹ̀; sùgbọ́n Pétérù sara gĺrí yọ ara rẹ̀ lákokò, nípasẹ̀ bẹ́ẹ̀ ò fi kóòtù rẹ̀ sílẹ̀ síbẹ̀.