Page:PeterRabbit1910.djvu/34

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ọ̀gbẹ́ni McGregor ńbẹ lórí àwọn ọwọ́ àti eékún rẹ̀ méjèèjì níbi tí ó ti ńgbin àwọn èso kábééjì, ṣùgbọ́n ní wàràǹsàsà ni ó tara gírí tí ó sì gbá tẹ̀lé Pétérù, tí ó sì ńna ohu-ìkéwéjo ọwọ́ rẹ̀ sí i tí ó sì ń pariwo tẹ̀le wípé, 'Dúró níbẹ̀, olè burúkú!'