Page:PeterRabbit1910.djvu/29

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Lákọ̀ọ́kọ́ níṣe ló jà àwọn ẹ̀fọ́ yanrin díẹ̀ jé tó sì sa ẹ̀wà Faransé mélòó kan sẹ́nu; lẹ́yìn èyín ni ó wú àwọn èso itakun díẹ̀ jẹ pẹ̀lú;