Page:PeterRabbit1910.djvu/26

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Sùgbón Peteru, tí ó jẹ́ elétí kunkun, súré gba ọ̀nà ọgbà Ọ̀gbẹ́ni McGregor lọ, ó sì fún ara rẹ̀ gba abẹ́ ona-àbáwolé ọgbà náà!