Page:PeterRabbit1910.djvu/22

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Báyìí ni Arúgbóbìnrin Ehoro mú apẹ̀ẹ̀rẹ̀ kan àti Ìbòrí-òjò rẹ̀, ló gba inú ijù lọ sọ́dọ̀ oní búrédì. Ò ra buredi aláwọ̀ jíjó kan ati buredi onírúurú ẹyọ márùn míràn.