Page:PeterRabbit1910.djvu/18

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


'Wàyìí o, ẹ̀yin omo mi,' arúgbóbìnrin Ehoro sọ fún wọn ní òwúrọ̀ ọjọ́ kan, 'ẹ le lọ sínú pápá tàbí gba ẹ̀bá ọ̀nà lọ, ṣùgbọ́n ẹ kò gbọdọ̀ wọ inú ọgbà Ògbẹ́ni McGregor: baba yín bá ìjàǹbá pàdé níbẹ̀; Arábìnrin McGregor fi sàsun.'