Page:PeterRabbit1910.djvu/17

From Wikiguage
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ní ayé àtijọ́, àwọn omo ehoro kékèké mẹ́rin kan ńbẹ, orúkọ wọn sì ni- Fílópísì, Mópísì, Onírù-òwú, ati Pétérù.

Wọ́n ń gbé pẹ̀lú ìyá wọn ninu ihò ilẹ̀, lábẹ́ gbòngbò igi-fírí ńlá kan.