Page:PeterRabbit1910.djvu/37

From Wikiguage
Revision as of 03:38, 2 June 2018 by Admin (talk | contribs)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)
Jump to: navigation, search
This page has been validated


Ìbẹ̀rù báá Pétérù gidigidi wọ inú akínyẹmí ara rẹ̀; ó sáré hílàholo kiri inú ọgbà náà, pàápàá bí ó ti jẹ́ wípé kò rántí bí yóò ti dé ọ̀nà-àbáwọlé rẹ̀ mọ́. Ó nuu ọ̀kan nínú àwọn bàtà rẹ̀ sáàrin àwọn èso kábééjì, ìkejì sì nù sáàrin oko òdùkú.